Gbogbo nkan ti adojuru jẹ pataki!
Ti nkan kan ba sọnu, a wa ko ni ni anfani lati pari adojuru na.
Ti nkan kan ba sọnu, a wa ko ni ni anfani lati pari adojuru na.
Ọlọrun da ọ bi eroja inu adojuru.
oje pataki inu ife Olorun.
Jesu kọwa lati pin ife na pẹlu gbogbo eniyan ti a ba pade!
Nigba miran awon eniyan yan lati ṣe iṣẹ buburu. Nigba ti eyi ba ṣẹlẹ, awọn eroja adojuru wọn ti sonu!
Nípa ṣíṣe iṣẹ rere, o le rii daju pe awọn eroja adojuru rẹ wa pẹlu Jesu nigbagbogbo!
Pin ife ti Olorun ti oni loni!
Nitori awa ni iṣẹ ọwọ́ rẹ̀ ti a ti dá ninu Kristi Jesu fun iṣẹ rere, ti Ọlọrun ti pèse tẹlẹ, ki awa ki o le mã rìn ninu wọn.
Efe 2:10
Efe 2:10
Mo ni ise lati se
(Ègbè)
Mo ni ise lati se
Mo ni ise lati se
JESU KRISTI TI fun mi
Nise lati se
Emi o bẹrẹ ọjọ mi
Nipa sisọ ÀDÚRÀ mi
Lati na ọwọ iranwọ
ATI lati fi hàn pé mo bikita
Mo maa fi fún àwọn
To nilo iranwọ
BOYA, aisan, aini, ailara
GBOGBO re bakana
(Ègbè)
Emi yoo gbe igbe aiye àpẹẹrẹ
Emi yoo yìn orukọ rẹ
Un o fun OJO mi gbegbe bi ẹbọ
FUN GBOGBO emi jìya
Emi o na ọwọ iranwọ
Maa beere lọwọ OLUWA
Lati tu wa sile lọwọ irora
(Ègbè)
Ran awọn alaini ile lowo
Awon ti won ti sọnu ati ti won ti reje
Mo maa kọ awon ỌMỌ mi
Bi ati se le se ranwọ na
Nife fun awọn arakunrin mi
ATI awon arabinrin mi na
OKankan wa un gbagbọ
A NÍ ise lati se ...
(Ègbè 2x)
Mo ni ise lati se
Mo ni ise lati se
JESU KRISTI TI fun mi
Nise lati se
(Ègbè)
Mo ni ise lati se
Mo ni ise lati se
JESU KRISTI TI fun mi
Nise lati se
Emi o bẹrẹ ọjọ mi
Nipa sisọ ÀDÚRÀ mi
Lati na ọwọ iranwọ
ATI lati fi hàn pé mo bikita
Mo maa fi fún àwọn
To nilo iranwọ
BOYA, aisan, aini, ailara
GBOGBO re bakana
(Ègbè)
Emi yoo gbe igbe aiye àpẹẹrẹ
Emi yoo yìn orukọ rẹ
Un o fun OJO mi gbegbe bi ẹbọ
FUN GBOGBO emi jìya
Emi o na ọwọ iranwọ
Maa beere lọwọ OLUWA
Lati tu wa sile lọwọ irora
(Ègbè)
Ran awọn alaini ile lowo
Awon ti won ti sọnu ati ti won ti reje
Mo maa kọ awon ỌMỌ mi
Bi ati se le se ranwọ na
Nife fun awọn arakunrin mi
ATI awon arabinrin mi na
OKankan wa un gbagbọ
A NÍ ise lati se ...
(Ègbè 2x)
Mo ni ise lati se
Mo ni ise lati se
JESU KRISTI TI fun mi
Nise lati se