Ohunkohun ti iba sele!
Olorun fẹràn re
Lalaini idi!
Awọn àṣàyàn rere meje yi ran wa lowo lati ni ipin ninu ife alaini idi Olorun
Nigbagbogbo ni ife je:
1. Ipamora: Ọlọrun duro fun o lati ṣe ipinu to tọ
2. Iwa pele: fẹ ọmọnikeji rẹ bi ara rẹ
3. Otito: So fun awon elomiran nipa ife Olorun fun wọn
4. Ifarada ohun gbogbo: Ọlọrun wa pẹlu nyin nigbati aye ba le fun ọ
5.Gba ohun gbogbo gbọ: Fi ife Ọlọrun han pẹlu gbogbo eniyan
6.Ni ireti ohun gbogbo: Ọlọrun ni ètò pataki kan fun aye re
7 Fi ara da ohun gbogbo: Ọlọrun yio maa ni ife re nigbagbogbo
Awọn wọnyi meje buburu ti maa n dena wa lati ni ipin ninu ife Ọlọrun
Ife kii se:
1. owú: Ma je owu ohun ti awọn miran ni
2. Igberaga: Maa so wipe o dara ju awọn miran lọ
3. ìmọtara eni nikan-: Má ṣe gbìyànjú láti gbe ohun gbogbo gba ọna ara rẹ
4. Arínifín: Má ṣe sọ tabi ṣe ohun búburú
5. Binu: Maa se binu sí ẹnikẹni pẹlu
6. Ibinu fufu: Maa se ni ikunsinu si elomiran
7. Sise asemase: Maa te oju ofin mole
1. owú: Ma je owu ohun ti awọn miran ni
2. Igberaga: Maa so wipe o dara ju awọn miran lọ
3. ìmọtara eni nikan-: Má ṣe gbìyànjú láti gbe ohun gbogbo gba ọna ara rẹ
4. Arínifín: Má ṣe sọ tabi ṣe ohun búburú
5. Binu: Maa se binu sí ẹnikẹni pẹlu
6. Ibinu fufu: Maa se ni ikunsinu si elomiran
7. Sise asemase: Maa te oju ofin mole
4Ifẹ a mã mu suru, a si mã ṣeun; ifẹ kì iṣe ilara; ifẹ kì isọrọ igberaga, kì ifẹ̀, 5Kì ihuwa aitọ́, kì iwá ohun ti ara rẹ̀, a kì imu u binu, bẹ̃ni kì igbiro ohun buburu; 6Kì iyọ̀ si aiṣododo, ṣugbọn a mã yọ̀ ninu otitọ; 7A mã farada ohun gbogbo, a mã gbà ohun gbogbo gbọ́, a mã reti ohun gbogbo, a mã fàiyarán ohun gbogbo.
1 Kor 13:4-7
Orin kiko: Ife alainidi
Bàbá Ọrun jọwọ gbọ adura wa kọ wa lati nifẹ rẹ ati pe ki o ran wa lati bikita Opọlọpọ lo ti sele O soro lati gbagbe ko ni anfani lati sisẹ ati di eni ahamọ nigba kan ri (Egbe 2x) Alainidi, Alainidi, Ife alainidi Arakunrin ati arabirin Bawo ni ase ma n dariji Fun un ni ibinu rẹ ki o si beere fun anfani O mọ wahala wa aniyan ati awọn ifiyesi wa Oun si ni idahun àpẹẹrẹ kan soso na (Egbe 2x) Ẹ jẹ ki a tẹle e (2x) fife awon aládùúgbò wa a ti ni ominira nipasẹ Jesu Olùgbàlà wa (Egbe 2x) |
Orin kiko: Ohunkohun ti baa de ... Mo nife re lalainidi
Lai tip e se hin ọjọ kan wa nigbati mo gbàgbo Mo da wa Mo kígbe ni iberu Mo si kún pẹlu itiju Nitori emi kò mọ ife ati Alafia ti o muwa Mo rìn ninu òkunkun Mi o si gbagbọ Pe mo le ni ominira Irora lile yi ........ ṣugbọn (Egbe 2x) Ohunkohun ti baa de Ohunkohun ti baa de Ohunkohun ti baa de Mo nife re lalainidi Mo ti gbadura si Ọlọrun lati tu mi sile Sibe mo si tun bẹru O ti romi pin Ṣugbọn o mu ọwọ mi o si wi fun mi pe Ko si ohunkohun Mo nife re lalainidi Bayi mo mọ wipe won feran mi Akoko si ti to fun mi lati tàn ogo lẹẹkansi (Egbe 4x) |