Ọmọ Ọlọrun ni ọ O si fẹràn rẹ pẹlu ifẹ alainidi!
O le gba igbala ayeraye nipa sisọ ọrọ wọnyi:
O le gba igbala ayeraye nipa sisọ ọrọ wọnyi:

"Jesu, o ku lati dari gbogbo awọn ese mi jimi.
O si ji dide kuro ninu okú lati fun mi ìyè ayérayé.
O ṣeun fun wiwa sinu aye mi ati igbala mi. Ran mi lowo lati dagba ninu ifẹ rẹ, Amin. "
Pe, bi iwọ ba fi ẹnu rẹ jẹwọ Jesu li Oluwa, ti iwọ si gbagbọ́ li ọkàn rẹ pe, Ọlọrun jí i dide kuro ninu okú, a o gbà ọ là.
Romu 10: 9
Oku oriire o! O oti da omo Olorun!
|
|
Orin: FI FUN JESU
FI FUN JÉSÙ Ó mọ orukọ re FI FUN JÉSÙ Gba ominira lowo irora FI FUN JÉSÙ Ominira wa fun o gba FI FUN JÉSÙ Akoko tito lati gbàgbo FI FUN JÉSÙ O fo ese re FI FUN JÉSÙ Ki osi di atunbi ègbè FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ Fi gbogbo re fun u FI FUN JÉSÙ Idahun si ye wa FI FUN JÉSÙ O si fọkàn RẸ bale lori ibẹrubojo re FI FUN JÉSÙ Iṣoro re ti lọ FI FUN JÉSÙ Kọ ọrin titun FI FUN JÉSÙ GBOGBO AYÉ RẸ fi fun u FI FUN JÉSÙ Ore re timotimo ni ègbè FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ Fi gbogbo re fun u FI FUN JÉSÙ O MO PÉ O LE SE FI FUN JÉSÙ Jẹ ki i o gba owo re FI FUN JÉSÙ IWỌ KO DAWA FI FUN JÉSÙ Oun yoo mu O rile FI FUN JÉSÙ EYI NI MO MỌ TÒÓTỌ FI FUN JÉSÙ IFE RE WA FUN O (Ègbè 2x) FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ FI GBOGBO RE FUN U ègbè FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ FI FUN JÉSÙ FI GBOGBO RE FUN U |
ORIN: Mo maa yìn orukọ rẹ
* (Egbe Akorin) (Ègbè) Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn i Nigbati mo sọnu * Nigbati mo sọnu Mo pe orukọ rẹ * Mo pe orukọ rẹ Nigbati mo sọnu * Nigbati mo sọnu Mo pe orukọ rẹ * Mo pe orukọ rẹ Nigbati mo sọnu * Nigbati mo sọnu Mo pe orukọ rẹ * Mo pe orukọ rẹ Nigbati mo sọnu * Mo pe orukọ rẹ Mo pe orukọ rẹ (Ègbè) Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn i O wẹ ese mi * O wẹ ese mi Osi sọ mi di mimọ * Osi ṣọ mi di mimọ O wẹ ese mi * O wẹ ese mi Osi ṣọ mi di mimọ *Osi ṣọ mi di mimọ O wẹ ese mi * O wẹ ese mi Osi ṣọ mi di mimọ * Osi ṣọ mi di mimọ O wẹ ese mi * Osi ṣọ mi di mimọ Osi ṣọ mi di mimọ (Ègbè) Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn i Mo ti deni itusile * Mo ti deni itusile O, Mo ti deni itusile * Mo ti deni itusile Mo ti deni itusile * Mo ti deni itusile O, Mo ti deni itusile * Mo ti deni itusile Mo ti deni itusile * Mo ti deni itusile O, Mo ti deni itusile * Mo ti deni itusile Mo ti deni itusile * Mo ti deni itusile Mo ti deni itusile (Ègbè 2x) Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn orukọ rẹ Mo maa yìn orukọ rẹ * Mo maa yìn i |