(English)
Jesu fẹràn re! Jẹ ki kun inu okan re loni!

Awọn afọju nriran, awọn amukun si nrìn, a nwẹ̀ awọn adẹtẹ̀ mọ́, awọn aditi ngbọràn, a njí awọn okú dide, a si nwasu ihinrere fun awọn òtoṣi.
Mat 11:5
Mat 11:5
Ohunkohun ti iba ti sele seyin,
O ti di eda titun ninu ife Jesu!
Nitorina bi ẹnikẹni ba wà ninu Kristi, o di ẹda titun: ohun atijọ ti kọja lọ; kiyesi i, nwọn si di titun.
2 Kor 5:17
O ti di eda titun ninu ife Jesu!
Nitorina bi ẹnikẹni ba wà ninu Kristi, o di ẹda titun: ohun atijọ ti kọja lọ; kiyesi i, nwọn si di titun.
2 Kor 5:17
Orin kiko: Ko si diduro mo, akoko tito lati wa si ile
O ti lọ fun saa kan. Bẹẹni nitõtọ O oti ti ri ohunkohun ṣugbọn aditu O ro wipe o le ṣe gbogbo rẹ fun rare. Ṣugbọn nisisiyi o ti ri Akoko tito lati wa si ile Nigbagbogbo lole wa ṣugbọn o n bẹru lati ṣii ilẹkùn si isegun Bayi ni akoko to lati korin jade lohun rara Ka si dupe ati lati yìn Oluwa wa to jinde. Jesu n ki wa kaabọ Pada si ile (Egbe) Ko si iduro mo ... Ko si iduro mo Ko si, Ko si, Ko si iduro mo Akoko tito lati wa si ile ... Akoko tito lati wa si ile Ko si iduro mo ... .Akoko tito lati wa si ile Mi o le gbagbọ bi inu mi ti dun lati ri aye mi kún pẹlu alafia ati ife re lẹẹkansi Jesu ni olugbala mi Oun na si ni ore mi Mo dupẹ lọwọ re Oluwa fun idahùn si adura O si mu ọmọ tosonu o si tẹwọgbà mi si ile (Egbe) Emi yoo gba wipe mo bẹru Lati fi ọkàn mi han ki o si jẹ ki O wole Ṣugbọn nisisiyi mo mọ Olugbala mi njọba Nitori Ọlọrun jade wa O si ipe wa pelu orukọ Jesu nki wa aabọ pada ile (Egbe 2x) |
Orin kiko: Mi o le yi igba ti o ti kọja pada
(Egbe) Mi o le yi igba ti o ti kọja pada ... .Nkan to ti ṣele ti ṣele Mi o le yi igba ti o ti kọja pada ... .Aye ti nyen ti lọ Mi o le yi igba ti o ti kọja pada ... Ṣugbọn pẹlu rẹ moni iwosàn Emi o si bẹrẹ ni otun Mo ṣe awọn asise kan Mo si ti se ipalara awon ọrẹ mi Ma binu, Oluwa fun awọn ohun ti mo ti ṣe Mo si ti kabamọ Pe emi ko le yipada Ṣugbọn emi mọ pe e maa ran mi lowo pelu oye (Egbe) Jesu fun mi laye o si tu mi sile O mu mi wole O si gba ọkàn mi la Mo si tun dara si bayi Nitori pe mo jẹ ki O wole Mo ni aye titun Mo le bẹrẹ (Egbe) Mi o le yi igba ti o ti kọja pada ... .Nkan ti o ti ṣele ti ṣele Mi o le yi igba ti o ti kọja pada ... .Aye yen ti koja lọ Mi o le yi igba ti o ti kọja pada ... Ṣugbọn pẹlu rẹ moni iwosàn Emi o si bẹrẹ ni titun Maa bẹrẹ ni titun (3x) (Egbe) |