
O le ṣe àṣàyàn ti o dara nipa kíkó Èso ti Ẹmí!
Jesu béèrè lowo wa je ki ọkàn wa kun fun Èso ti Ẹmí nipa ṣiṣe àṣàyàn awọn oun ti o dara!

Mo yan Ife nigbati mo ba fanimọra!

Mo yan Ayo nigbati mo ba nrerin!

Mo ti yan Alafia nigbati mo wipe, "E maa binu!"

Mo ti yan Ipamora nigbati mo duro de akoko mi!

Mo yan Iwa pele nigbati mo je alajopin pẹlu awọn elomiran!

Mo yan Isore nigbati mo sọ òtítọ!

Mo yan Igbagbọ nigbati mo sọrọ si Olorun ninu adura!

Mo yan Iwa tutu nigba ti mo yan lati ran awon elomiran lọwọ!

Mo yan Ikora eni nijanu nigbati mo tẹle awọn itọnisọna!
Iwuri loje fun Jesu ati wipe O si fẹràn re gidigidi!
Ranti lati beere lọwọ Jesu lati ran ọ lọwọ lati yan oun ti odara nipa mimu ki Eso Emi ole kun nu ọkan re!