Baba wa ti mbe li orun; Ki a bòwo fun oruko re Ki Ijobe re de; Ife tire ni ki a se, bi ti orun beni li aiye Fun wa li onje ojo wa loni Dari gbese wa ji wa, bi awa ti ndariji awon onogbese wa Má si fi wa sinu idewò, sugbon gbà wa lowo bilisi Nitori ijoba ni tire ati agbara ati ogo lailai. Amin. Matteu 6: 9-13 |
Jésù kọni pé:
Ọlọrun jẹ Mímọ.
Ijọba Olorun nbọ lori aiye.
Ife Olorun ni ki ase.
Ọlọrun pese fun aini mi ojoojumọ.
Ọlọrun dárí ese mi jimi.
Ọlọrun ràn mi lowo lati idariji elomiiran.
Ọlọrun ràn mi lọwọ lati kọ idanwo.
Ọlọrun gbà mi kuro lọwọ ibi.

Smiley wí pé:
Mo le fi ọwọ wọ orúkọ Ọlọrun.
Mo le wo iwaju si ọjọ ti Jesu yoo pada wa.
Mo le beere lọwọ Ọlọrun lati fi han mi bi ati nse àṣàyàn rere.
Mo le gbẹkẹlé Ọlọrun pe yóò pese fun aini mi (kiise ife inu mi).
Mo le gbagbo pe Olorun dárí ẹṣẹ mi jimi nigbati mo ba bebe.
Mo le beere lọwọ Ọlọrun láti ràn mi lọwọ lati ma dari ese ji awon elomiran.
Mo le beere lọwọ Ọlọrun láti ràn mi lọwọ lati mase bọ sinu wahala.
Mo le beere lọwọ Ọlọrun lati dabobo mi ni gbogbo igba.

Orin: ǸJẸ o Gbàgbọ?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... NINu ỌRỌ OF OLORUN?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... NINU majemu?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... ninu ibi wundia?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... NINU ỌRỌ DI ARA?
(Ègbè)
O, JESU O MO PÉ MO GBAGBO
O, JESU O MO PÉ MO GBAGBO
O, JESU O MO PÉ MO GBAGBO
Mo ti Gbàgbọ, mo Gbàgbọ, mo ti Gbagbo
ǸJẸ o Gbàgbọ … wipe o ku fun mi?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... wipe o jinde pada?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... Pe Ó dárí gbogbo ese re ji?
SÉ O Gbàgbọ ... ninu isegun re?
(Ègbè)
ǸJẸ o Gbàgbọ ... ninu Ẹmi Mimọ?
ǸJẸ o Gbàgbọ ...ninu iṣẹ agbara rẹ?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... ninu ọrun loke?
ǸJẸ o Gbàgbọ ... ninu IFE olugbala wa?
(Ègbè 3x)