Fi àmure otitọ di ẹgbẹ nyin!
Jesu n fe o lati mọ otitọ bi oti fẹràn re!

Gbe ìgbaiya ododo wo!
Jesu béèrè owo re lati so otito ati lati maa ṣe ohun ti o jẹ ododo!

Wọ bata alafia !
Nigba ti o ba fi Alafia han si awọn enia,
o kọ wọn nípa Ife Ọlọrun ninu re!

Fi apata igbagbọ́ wo.
Igbagbo re ninu Jesu mu ki Èṣù sa fun mi!

Wo aṣibori igbala.
Jesu ku lori agbelebu osi jii dide kuro ninu okú lati gba ọ la.
Jesu yoo ma wa ni ẹgbẹ rẹ lati ran ọ lowo ninu isoro re!

Wo idà ti Ẹmí.
Nigbakugba ti o ba gbadura, agbara ti ife Olorun wa ni inu re!

Efesu 6:11-18
Ẹ gbe gbogbo ihamọra Ọlọrun wọ̀, ki ẹnyin ki o le kọ oju ija si arekereke Eṣu. 12Nitoripe kì iṣe ẹ̀jẹ ati ẹran-ara li awa mba jijakadi, ṣugbọn awọn ijoye, awọn ọlọla, awọn alaṣẹ ibi òkunkun aiye yi, ati awọn ẹmí buburu ni oju ọrun. 13Nitorina ẹ gbe gbogbo ihamọra Ọlọrun wọ̀ ki ẹnyin ki o le duro tiri si ọjọ ibi, nigbati ẹnyin bá si ti ṣe ohun gbogbo tan, ki ẹ si duro. 14Ẹ duro nitorina lẹhin ti ẹ ti fi àmure otitọ di ẹgbẹ nyin, ti ẹ si ti di ìgbaiya ododo nì mọra; 15Ti ẹ si ti fi imura ihinrere alafia wọ̀ ẹsẹ nyin ni bàta; 16Léke gbogbo rẹ̀, ẹ mu apata igbagbọ́, nipa eyiti ẹnyin ó le mã fi paná gbogbo ọfa iná ẹni ibi nì. 17Ki ẹ si mu aṣibori igbala, ati idà Ẹmí, ti iṣe ọ̀rọ Ọlọrun: 18Pẹlu gbogbo adura ati ẹbẹ ni ki ẹ mã gbadura nigbagbogbo ninu Ẹmí, ki ẹ si mã ṣọra si i ninu iduroṣinṣin gbogbo, ati ẹ̀bẹ fun gbogbo enia mimọ́;

Orin : GBOORO ... LALAISI IRAN WIWO
Ràn mí lọwọ Oluwa,
Mo nilo iranwọ
Fun Eto igbese
Jakejado ọjọ
Idanwo ati yapa wa simi
Nipase GBOGBO orisirisi wonyi
Mo beere lowo re OLUWA,
Lati fihan mi bi
BÍBÉLÌ RẸ sele ye mi
Ki o si ràn mí lowo Oluwa,
Lati ka ỌRỌ RẸ
Mo MO PÉ Mo le se
(Ègbè)
Ririn GBOORO
Kii se, sosi tabi sọtun
Mo n ṣiṣi lo FUN IGBALA
Ràn mí lowo Oluwa,
Lati tẹle ọna Re
GBOORO, lalais iran wiwo
Kọ mi OLUWA,
Lati tẹle ọna RẸ
Kin si tun le je imole fun awon miiran
Mo SETAN lati
Di eni omnira kuro ninu ẹṣẹ
Kin si jókòó si tabili rẹ
(Ègbè)
Èmí SETAN lati gbadura
Ni ojo oni gan
Lati PAMIMỌ KURO ninu wahala
O ṣeun Oluwa,
Fun didari ese mi
Ni ọnà ti o GBOORO TI o si tun je tooro
(Ègbè 2x)
Ràn mí lọwọ Oluwa,
Mo nilo iranwọ
Fun Eto igbese
Jakejado ọjọ
Idanwo ati yapa wa simi
Nipase GBOGBO orisirisi wonyi
Mo beere lowo re OLUWA,
Lati fihan mi bi
BÍBÉLÌ RẸ sele ye mi
Ki o si ràn mí lowo Oluwa,
Lati ka ỌRỌ RẸ
Mo MO PÉ Mo le se
(Ègbè)
Ririn GBOORO
Kii se, sosi tabi sọtun
Mo n ṣiṣi lo FUN IGBALA
Ràn mí lowo Oluwa,
Lati tẹle ọna Re
GBOORO, lalais iran wiwo
Kọ mi OLUWA,
Lati tẹle ọna RẸ
Kin si tun le je imole fun awon miiran
Mo SETAN lati
Di eni omnira kuro ninu ẹṣẹ
Kin si jókòó si tabili rẹ
(Ègbè)
Èmí SETAN lati gbadura
Ni ojo oni gan
Lati PAMIMỌ KURO ninu wahala
O ṣeun Oluwa,
Fun didari ese mi
Ni ọnà ti o GBOORO TI o si tun je tooro
(Ègbè 2x)